-
Jóṣúà 9:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 wọ́n tún wọ bàtà tó ti gbó, tí wọ́n sì ti lẹ̀, aṣọ ọrùn wọn náà ti gbó. Gbogbo búrẹ́dì tí wọ́n gbé dání ti gbẹ, ó sì ti ń rún.