-
Jóṣúà 8:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Lẹ́yìn tí Ísírẹ́lì pa gbogbo àwọn tó ń gbé ìlú Áì tán níbi gbalasa, nínú aginjù tí wọ́n lé wọn lọ, tí wọ́n sì ti fi idà pa gbogbo wọn láìṣẹ́ ku ẹnì kan, gbogbo Ísírẹ́lì pa dà sí Áì, wọ́n sì fi idà pa á run.
-