-
Diutarónómì 3:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Jèhófà wá sọ fún mi pé, ‘Má bẹ̀rù rẹ̀, torí màá fi òun àti gbogbo èèyàn rẹ̀ àti ilẹ̀ rẹ̀ lé ọ lọ́wọ́; ohun tí o sì ṣe sí Síhónì, ọba àwọn Ámórì tó gbé ní Hẹ́ṣíbónì ni wàá ṣe sí i.’
-
-
Diutarónómì 20:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 “Tí o bá lọ bá àwọn ọ̀tá rẹ jagun, tí o sì rí àwọn ẹṣin, àwọn kẹ̀kẹ́ ẹṣin àti àwọn ọmọ ogun wọn tí wọ́n pọ̀ rẹpẹtẹ jù ọ́ lọ, má bẹ̀rù wọn, torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ tó mú ọ kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì wà pẹ̀lú rẹ.+
-