Nọ́ńbà 27:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Mú Jóṣúà ọmọ Núnì, ọkùnrin tí ẹ̀mí wà nínú rẹ̀, kí o sì gbé ọwọ́ rẹ lé e.+ Nọ́ńbà 27:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Kí o sì fún un+ lára àṣẹ* tí o ní, kí gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì lè máa gbọ́ tirẹ̀.+ Diutarónómì 34:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ẹ̀mí ọgbọ́n sì kún inú Jóṣúà ọmọ Núnì torí Mósè ti gbé ọwọ́ lé e;+ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wá ń fetí sí i, wọ́n sì ṣe ohun tí Jèhófà pa láṣẹ fún Mósè gẹ́lẹ́.+
18 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Mú Jóṣúà ọmọ Núnì, ọkùnrin tí ẹ̀mí wà nínú rẹ̀, kí o sì gbé ọwọ́ rẹ lé e.+
9 Ẹ̀mí ọgbọ́n sì kún inú Jóṣúà ọmọ Núnì torí Mósè ti gbé ọwọ́ lé e;+ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wá ń fetí sí i, wọ́n sì ṣe ohun tí Jèhófà pa láṣẹ fún Mósè gẹ́lẹ́.+