2 Sámúẹ́lì 1:17, 18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Dáfídì wá kọ orin arò* yìí nítorí Sọ́ọ̀lù àti Jónátánì ọmọ rẹ̀,+ 18 ó sì ní kí wọ́n kọ́ àwọn èèyàn Júdà ní orin arò tí wọ́n pè ní “Ọrun,” tó wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé Jáṣárì:+
17 Dáfídì wá kọ orin arò* yìí nítorí Sọ́ọ̀lù àti Jónátánì ọmọ rẹ̀,+ 18 ó sì ní kí wọ́n kọ́ àwọn èèyàn Júdà ní orin arò tí wọ́n pè ní “Ọrun,” tó wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé Jáṣárì:+