-
Àwọn Onídàájọ́ 3:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Ó wá sọ fún wọn pé: “Ẹ tẹ̀ lé mi, torí Jèhófà ti fi àwọn ọ̀tá yín, àwọn ọmọ Móábù, lé yín lọ́wọ́.” Torí náà, wọ́n tẹ̀ lé e, wọ́n sì gba ibi tó ṣeé fẹsẹ̀ gbà kọjá ní odò Jọ́dánì mọ́ àwọn ọmọ Móábù lọ́wọ́, wọn ò sì jẹ́ kí ẹnikẹ́ni kọjá.
-
-
Àwọn Onídàájọ́ 12:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Gílíádì wá gba ibi tó ṣeé fẹsẹ̀ gbà kọjá nínú odò Jọ́dánì+ mọ́ Éfúrémù lọ́wọ́; nígbà tí àwọn ọkùnrin Éfúrémù sì ń wá bí wọ́n á ṣe sá lọ, wọ́n á sọ pé: “Ẹ jẹ́ kí n sọdá”; àwọn ọkùnrin Gílíádì á wá bi wọ́n níkọ̀ọ̀kan pé: “Ṣé ọmọ Éfúrémù ni ọ́?” Tó bá fèsì pé, “Rárá!”
-