Diutarónómì 2:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 “‘Ẹ dìde, kí ẹ sì rí i pé ẹ sọdá Àfonífojì Áánónì.+ Wò ó, mo ti fi Síhónì+ ọba Hẹ́ṣíbónì, tó jẹ́ Ámórì lé yín lọ́wọ́. Torí náà, ẹ bẹ̀rẹ̀ sí í gba ilẹ̀ rẹ̀, kí ẹ sì bá a jagun.
24 “‘Ẹ dìde, kí ẹ sì rí i pé ẹ sọdá Àfonífojì Áánónì.+ Wò ó, mo ti fi Síhónì+ ọba Hẹ́ṣíbónì, tó jẹ́ Ámórì lé yín lọ́wọ́. Torí náà, ẹ bẹ̀rẹ̀ sí í gba ilẹ̀ rẹ̀, kí ẹ sì bá a jagun.