Ẹ́kísódù 14:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ni Mósè bá na ọwọ́ rẹ̀ sórí òkun;+ Jèhófà sì mú kí atẹ́gùn líle fẹ́ wá láti ìlà oòrùn ní gbogbo òru yẹn, ó sì bi òkun náà sẹ́yìn. Ó mú kí ìsàlẹ̀ òkun di ilẹ̀ gbígbẹ,+ omi náà sì pínyà.+ Ẹ́kísódù 15:13, 14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 O fi ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ ṣamọ̀nà àwọn èèyàn tí o rà pa dà;+ Ìwọ yóò fi agbára rẹ darí wọn lọ sí ibùgbé rẹ mímọ́. 14 Àwọn èèyàn gbọ́dọ̀ gbọ́,+ jìnnìjìnnì á bò wọ́n; Àwọn tó ń gbé Filísíà máa jẹ̀rora.*
21 Ni Mósè bá na ọwọ́ rẹ̀ sórí òkun;+ Jèhófà sì mú kí atẹ́gùn líle fẹ́ wá láti ìlà oòrùn ní gbogbo òru yẹn, ó sì bi òkun náà sẹ́yìn. Ó mú kí ìsàlẹ̀ òkun di ilẹ̀ gbígbẹ,+ omi náà sì pínyà.+
13 O fi ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ ṣamọ̀nà àwọn èèyàn tí o rà pa dà;+ Ìwọ yóò fi agbára rẹ darí wọn lọ sí ibùgbé rẹ mímọ́. 14 Àwọn èèyàn gbọ́dọ̀ gbọ́,+ jìnnìjìnnì á bò wọ́n; Àwọn tó ń gbé Filísíà máa jẹ̀rora.*