Jóṣúà 8:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ó gbé ọba Áì kọ́ sórí òpó igi* títí di ìrọ̀lẹ́, nígbà tí oòrùn sì ti fẹ́ wọ̀, Jóṣúà pàṣẹ pé kí wọ́n sọ òkú rẹ̀ kalẹ̀ látorí òpó igi.+ Wọ́n sì jù ú síbi àbáwọlé ẹnubodè ìlú náà, wọ́n kó òkúta lé e lórí pelemọ, ó sì wà níbẹ̀ títí dòní.
29 Ó gbé ọba Áì kọ́ sórí òpó igi* títí di ìrọ̀lẹ́, nígbà tí oòrùn sì ti fẹ́ wọ̀, Jóṣúà pàṣẹ pé kí wọ́n sọ òkú rẹ̀ kalẹ̀ látorí òpó igi.+ Wọ́n sì jù ú síbi àbáwọlé ẹnubodè ìlú náà, wọ́n kó òkúta lé e lórí pelemọ, ó sì wà níbẹ̀ títí dòní.