Ẹ́kísódù 23:29, 30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Mi ò ní lé wọn kúrò níwájú yín láàárín ọdún kan, kí ilẹ̀ náà má bàa di ahoro, kí àwọn ẹranko búburú má bàa pọ̀ níbẹ̀ kí wọ́n sì ṣe yín lọ́ṣẹ́.+ 30 Díẹ̀díẹ̀ ni màá lé wọn kúrò níwájú yín, títí ẹ ó fi bí àwọn ọmọ, tí ẹ ó sì gba ilẹ̀ náà.+
29 Mi ò ní lé wọn kúrò níwájú yín láàárín ọdún kan, kí ilẹ̀ náà má bàa di ahoro, kí àwọn ẹranko búburú má bàa pọ̀ níbẹ̀ kí wọ́n sì ṣe yín lọ́ṣẹ́.+ 30 Díẹ̀díẹ̀ ni màá lé wọn kúrò níwájú yín, títí ẹ ó fi bí àwọn ọmọ, tí ẹ ó sì gba ilẹ̀ náà.+