Hébérù 11:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ìgbàgbọ́ Ráhábù aṣẹ́wó kò jẹ́ kó ṣègbé pẹ̀lú àwọn tó ṣàìgbọràn, torí ó gba àwọn amí náà tọwọ́tẹsẹ̀.+
31 Ìgbàgbọ́ Ráhábù aṣẹ́wó kò jẹ́ kó ṣègbé pẹ̀lú àwọn tó ṣàìgbọràn, torí ó gba àwọn amí náà tọwọ́tẹsẹ̀.+