Nọ́ńbà 33:48, 49 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 48 Níkẹyìn, wọ́n kúrò ní àwọn òkè Ábárímù, wọ́n sì pàgọ́ sí aṣálẹ̀ tó tẹ́jú ní Móábù, lẹ́gbẹ̀ẹ́ Jọ́dánì ní Jẹ́ríkò.+ 49 Wọ́n wá ń pàgọ́ sẹ́gbẹ̀ẹ́ Jọ́dánì láti Bẹti-jẹ́ṣímótì títí lọ dé Ebẹli-ṣítímù,+ ní aṣálẹ̀ tó tẹ́jú ní Móábù.
48 Níkẹyìn, wọ́n kúrò ní àwọn òkè Ábárímù, wọ́n sì pàgọ́ sí aṣálẹ̀ tó tẹ́jú ní Móábù, lẹ́gbẹ̀ẹ́ Jọ́dánì ní Jẹ́ríkò.+ 49 Wọ́n wá ń pàgọ́ sẹ́gbẹ̀ẹ́ Jọ́dánì láti Bẹti-jẹ́ṣímótì títí lọ dé Ebẹli-ṣítímù,+ ní aṣálẹ̀ tó tẹ́jú ní Móábù.