-
Jóṣúà 2:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Àwọn ọkùnrin náà sọ fún un pé: “A máa fi ẹ̀mí wa dí tiyín!* Tí o kò bá sọ ohun tí a wá ṣe, a máa fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn, a sì máa jẹ́ olóòótọ́ sí ọ nígbà tí Jèhófà bá fún wa ní ilẹ̀ náà.”
-