Jẹ́nẹ́sísì 23:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Sérà kú sí Kiriati-ábà,+ ìyẹn Hébúrónì,+ ní ilẹ̀ Kénáánì.+ Ábúráhámù wá bẹ̀rẹ̀ sí í ṣọ̀fọ̀, ó sì ń sunkún nítorí Sérà.
2 Sérà kú sí Kiriati-ábà,+ ìyẹn Hébúrónì,+ ní ilẹ̀ Kénáánì.+ Ábúráhámù wá bẹ̀rẹ̀ sí í ṣọ̀fọ̀, ó sì ń sunkún nítorí Sérà.