-
Jóṣúà 18:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Apá gúúsù bẹ̀rẹ̀ láti ìkángun Kiriati-jéárímù, ààlà náà sì lọ sápá ìwọ̀ oòrùn; ó dé ibi ìsun omi Néfítóà.+
-
-
Jóṣúà 18:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Jọ́dánì sì ni ààlà rẹ̀ lápá ìlà oòrùn. Èyí ni ogún àwọn àtọmọdọ́mọ Bẹ́ńjámínì ní ìdílé-ìdílé, gẹ́gẹ́ bí àwọn ààlà rẹ̀ yí ká.
-