44 Síbẹ̀, wọ́n ṣorí kunkun, wọ́n sì lọ sí orí òkè+ náà, àmọ́ àpótí májẹ̀mú Jèhófà àti Mósè kò kúrò ní àárín ibùdó.+ 45 Àwọn ọmọ Ámálékì àti àwọn ọmọ Kénáánì tí wọ́n ń gbé ní òkè yẹn wá sọ̀ kalẹ̀, wọ́n bá wọn jà, wọ́n sì ń tú wọn ká títí lọ dé Hóómà.+