1 Sámúẹ́lì 17:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Àwọn Filísínì+ kó àwọn ọmọ ogun* wọn jọ láti jagun. Wọ́n kóra jọ sí Sókọ̀+ ti ilẹ̀ Júdà, wọ́n sì dó sí àárín Sókọ̀ àti Ásékà,+ ní Efesi-dámímù.+
17 Àwọn Filísínì+ kó àwọn ọmọ ogun* wọn jọ láti jagun. Wọ́n kóra jọ sí Sókọ̀+ ti ilẹ̀ Júdà, wọ́n sì dó sí àárín Sókọ̀ àti Ásékà,+ ní Efesi-dámímù.+