-
Jóṣúà 10:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Jóṣúà àti gbogbo Ísírẹ́lì wá kúrò ní Mákédà lọ sí Líbínà, wọ́n sì bá Líbínà+ jà.
-
-
2 Àwọn Ọba 8:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Àmọ́ Édómù ṣì ń ṣọ̀tẹ̀ sí Júdà títí di òní yìí. Líbínà+ pẹ̀lú ṣọ̀tẹ̀ ní àkókò yẹn.
-