Jóṣúà 4:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ní ọjọ́ yẹn, Jèhófà gbé Jóṣúà ga níṣojú gbogbo Ísírẹ́lì,+ wọ́n sì bọ̀wọ̀ fún un gan-an* ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀, bí wọ́n ṣe bọ̀wọ̀ fún Mósè gidigidi.+
14 Ní ọjọ́ yẹn, Jèhófà gbé Jóṣúà ga níṣojú gbogbo Ísírẹ́lì,+ wọ́n sì bọ̀wọ̀ fún un gan-an* ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀, bí wọ́n ṣe bọ̀wọ̀ fún Mósè gidigidi.+