-
Nọ́ńbà 26:29-32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Àwọn ọmọ Mánásè+ nìyí: látọ̀dọ̀ Mákírù,+ ìdílé àwọn ọmọ Mákírù; Mákírù wá bí Gílíádì;+ látọ̀dọ̀ Gílíádì, ìdílé àwọn ọmọ Gílíádì. 30 Àwọn ọmọ Gílíádì nìyí: látọ̀dọ̀ Yésérì, ìdílé àwọn ọmọ Yésérì; látọ̀dọ̀ Hélékì, ìdílé àwọn ọmọ Hélékì; 31 látọ̀dọ̀ Ásíríélì, ìdílé àwọn ọmọ Ásíríélì; látọ̀dọ̀ Ṣékémù, ìdílé àwọn ọmọ Ṣékémù; 32 látọ̀dọ̀ Ṣẹ́mídà, ìdílé àwọn ọmọ Ṣẹ́mídà; látọ̀dọ̀ Héfà, ìdílé àwọn ọmọ Héfà.
-