Diutarónómì 7:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Má gbọ̀n rìrì nítorí wọn, torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ wà pẹ̀lú rẹ,+ Ọlọ́run tó tóbi ni, tó sì yẹ lẹ́ni tí à ń bẹ̀rù.+
21 Má gbọ̀n rìrì nítorí wọn, torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ wà pẹ̀lú rẹ,+ Ọlọ́run tó tóbi ni, tó sì yẹ lẹ́ni tí à ń bẹ̀rù.+