2 “Mú ọkùnrin méjìlá (12) láàárín àwọn èèyàn náà, ọkùnrin kan látinú ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan,+ 3 kí o sì pàṣẹ fún wọn pé: ‘Ẹ gbé òkúta méjìlá (12) ní àárín Jọ́dánì, níbi tí ẹsẹ̀ àwọn àlùfáà tó dúró sójú kan wà,+ kí ẹ gbé àwọn òkúta náà dání, kí ẹ sì tò wọ́n síbi tí ẹ máa sùn mọ́jú.’”+