ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 33:53
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 53 Ẹ ó gba ilẹ̀ náà, ẹ ó sì máa gbé níbẹ̀, torí ó dájú pé màá fún yín ní ilẹ̀ náà kó lè di tiyín.+

  • Jóṣúà 20:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Torí náà, wọ́n ya Kédéṣì+ ní Gálílì sọ́tọ̀* ní agbègbè olókè Náfútálì, Ṣékémù+ ní agbègbè olókè Éfúrémù àti Kiriati-ábà,+ ìyẹn Hébúrónì, ní agbègbè olókè Júdà.

  • Àwọn Onídàájọ́ 4:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Abẹ́ igi ọ̀pẹ Dèbórà ló máa ń jókòó sí, láàárín Rámà+ àti Bẹ́tẹ́lì,+ ní agbègbè olókè Éfúrémù; àwọn ọmọ Ísírẹ́lì máa ń kó ẹjọ́ wọn lọ bá a.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́