Sáàmù 66:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ó sọ òkun di ilẹ̀ gbígbẹ;+Wọ́n fi ẹsẹ̀ la odò kọjá.+ Níbẹ̀, à ń yọ̀ nítorí ohun tó ṣe.+