Jẹ́nẹ́sísì 49:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 “Oúnjẹ* Áṣérì+ yóò pọ̀ gan-an,* yóò sì pèsè oúnjẹ tó tọ́ sí ọba.+