Àwọn Onídàájọ́ 1:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Náfútálì ò lé àwọn tó ń gbé Bẹti-ṣémẹ́ṣì àti àwọn tó ń gbé Bẹti-ánátì+ kúrò, wọ́n ṣì ń gbé láàárín àwọn ọmọ Kénáánì tó ń gbé ilẹ̀ náà.+ Wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í fipá kó àwọn tó ń gbé Bẹti-ṣémẹ́ṣì àti Bẹti-ánátì ṣiṣẹ́ àṣekára.
33 Náfútálì ò lé àwọn tó ń gbé Bẹti-ṣémẹ́ṣì àti àwọn tó ń gbé Bẹti-ánátì+ kúrò, wọ́n ṣì ń gbé láàárín àwọn ọmọ Kénáánì tó ń gbé ilẹ̀ náà.+ Wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í fipá kó àwọn tó ń gbé Bẹti-ṣémẹ́ṣì àti Bẹti-ánátì ṣiṣẹ́ àṣekára.