Nọ́ńbà 35:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Torí ìlú ààbò rẹ̀ ló gbọ́dọ̀ máa gbé títí àlùfáà àgbà fi máa kú. Àmọ́ tí àlùfáà àgbà bá ti kú, apààyàn náà lè pa dà sí ilẹ̀ rẹ̀.+
28 Torí ìlú ààbò rẹ̀ ló gbọ́dọ̀ máa gbé títí àlùfáà àgbà fi máa kú. Àmọ́ tí àlùfáà àgbà bá ti kú, apààyàn náà lè pa dà sí ilẹ̀ rẹ̀.+