Nọ́ńbà 35:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Látinú ohun ìní àwọn ọmọ Ísírẹ́lì+ ni kí ẹ ti fún wọn ní àwọn ìlú náà. Kí ẹ gba púpọ̀ lọ́wọ́ àwùjọ tó pọ̀, kí ẹ sì gba díẹ̀+ lọ́wọ́ àwùjọ tó kéré. Kí àwùjọ kọ̀ọ̀kan fún àwọn ọmọ Léfì lára àwọn ìlú rẹ̀ bí ogún tó gbà bá ṣe pọ̀ tó.”
8 Látinú ohun ìní àwọn ọmọ Ísírẹ́lì+ ni kí ẹ ti fún wọn ní àwọn ìlú náà. Kí ẹ gba púpọ̀ lọ́wọ́ àwùjọ tó pọ̀, kí ẹ sì gba díẹ̀+ lọ́wọ́ àwùjọ tó kéré. Kí àwùjọ kọ̀ọ̀kan fún àwọn ọmọ Léfì lára àwọn ìlú rẹ̀ bí ogún tó gbà bá ṣe pọ̀ tó.”