-
Nọ́ńbà 35:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ní ẹ̀yìn ìlú náà, kí ẹ wọn ẹgbẹ̀rún méjì (2,000) ìgbọ̀nwọ́ ní apá ìlà oòrùn, ẹgbẹ̀rún méjì (2,000) ìgbọ̀nwọ́ ní apá gúúsù, ẹgbẹ̀rún méjì (2,000) ìgbọ̀nwọ́ ní apá ìwọ̀ oòrùn àti ẹgbẹ̀rún méjì (2,000) ìgbọ̀nwọ́ ní apá àríwá, kí ìlú náà wà ní àárín. Ìwọ̀nyí ló máa jẹ́ ibi ìjẹko àwọn ìlú náà.
-