-
Jóṣúà 19:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Ààlà wọn sì ni Hélíkátì,+ Hálì, Béténì, Ákíṣáfù,
-
-
Jóṣúà 19:31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 Èyí ni ogún ẹ̀yà Áṣérì ní ìdílé-ìdílé.+ Èyí sì ni àwọn ìlú náà pẹ̀lú àwọn ìgbèríko wọn.
-