Jóṣúà 21:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Wọ́n fún àwọn ọmọ Mérárì+ ní ìlú méjìlá (12) ní ìdílé-ìdílé látinú ìpín ẹ̀yà Rúbẹ́nì, ẹ̀yà Gádì àti ẹ̀yà Sébúlúnì.+
7 Wọ́n fún àwọn ọmọ Mérárì+ ní ìlú méjìlá (12) ní ìdílé-ìdílé látinú ìpín ẹ̀yà Rúbẹ́nì, ẹ̀yà Gádì àti ẹ̀yà Sébúlúnì.+