Jóṣúà 19:10, 11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Lẹ́yìn náà, kèké kẹta+ mú àwọn àtọmọdọ́mọ Sébúlúnì+ ní ìdílé-ìdílé, ààlà ogún wọn sì lọ títí dé Sárídì. 11 Ààlà wọn lọ sápá òkè ní ìwọ̀ oòrùn sí Márálà, ó dé Dábéṣétì, ó sì lọ sí àfonífojì tó wà níwájú Jókínéámù.
10 Lẹ́yìn náà, kèké kẹta+ mú àwọn àtọmọdọ́mọ Sébúlúnì+ ní ìdílé-ìdílé, ààlà ogún wọn sì lọ títí dé Sárídì. 11 Ààlà wọn lọ sápá òkè ní ìwọ̀ oòrùn sí Márálà, ó dé Dábéṣétì, ó sì lọ sí àfonífojì tó wà níwájú Jókínéámù.