Àwọn Onídàájọ́ 1:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Sébúlúnì ò lé àwọn tó ń gbé Kítírónì kúrò àti àwọn tó ń gbé Náhálólì.+ Àwọn ọmọ Kénáánì ṣì ń gbé láàárín wọn, wọ́n sì ń fipá kó wọn ṣiṣẹ́ àṣekára.+
30 Sébúlúnì ò lé àwọn tó ń gbé Kítírónì kúrò àti àwọn tó ń gbé Náhálólì.+ Àwọn ọmọ Kénáánì ṣì ń gbé láàárín wọn, wọ́n sì ń fipá kó wọn ṣiṣẹ́ àṣekára.+