1 Kíróníkà 6:80, 81 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 80 látinú ẹ̀yà Gádì, Rámótì ní Gílíádì pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀, Máhánáímù+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀, 81 Hẹ́ṣíbónì+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀ àti Jásérì+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀.
80 látinú ẹ̀yà Gádì, Rámótì ní Gílíádì pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀, Máhánáímù+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀, 81 Hẹ́ṣíbónì+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀ àti Jásérì+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀.