-
Diutarónómì 4:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Àmọ́ gbogbo ẹ̀yin tí ẹ rọ̀ mọ́ Jèhófà Ọlọ́run yín lẹ wà láàyè lónìí.
-
-
Diutarónómì 10:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 “Jèhófà Ọlọ́run rẹ ni kí o máa bẹ̀rù, òun ni kí o máa sìn,+ òun ni kí o rọ̀ mọ́, orúkọ rẹ̀ sì ni kí o máa fi búra.
-
-
Jóṣúà 23:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Àmọ́ kí ẹ rọ̀ mọ́ Jèhófà Ọlọ́run yín,+ bí ẹ ṣe ṣe títí dòní.
-