-
Jóṣúà 4:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe ohun tí Jóṣúà sọ gẹ́lẹ́. Wọ́n gbé òkúta méjìlá (12) ní àárín Jọ́dánì, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún Jóṣúà, iye òkúta náà jẹ́ iye ẹ̀yà àwọn ọmọ Ísírẹ́lì. Wọ́n kó o lọ síbi tí wọ́n fẹ́ sùn mọ́jú, wọ́n sì tò ó síbẹ̀.
-