Jóṣúà 13:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ní báyìí, Jóṣúà ti darúgbó, ó sì ti lọ́jọ́ lórí.+ Jèhófà sọ fún un pé: “O ti darúgbó, o sì ti lọ́jọ́ lórí; àmọ́ ẹ ò tíì gba* èyí tó pọ̀ jù nínú ilẹ̀ náà.
13 Ní báyìí, Jóṣúà ti darúgbó, ó sì ti lọ́jọ́ lórí.+ Jèhófà sọ fún un pé: “O ti darúgbó, o sì ti lọ́jọ́ lórí; àmọ́ ẹ ò tíì gba* èyí tó pọ̀ jù nínú ilẹ̀ náà.