Diutarónómì 11:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Jèhófà máa lé gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè yìí kúrò níwájú yín,+ ẹ sì máa lé àwọn orílẹ̀-èdè tó tóbi, tí wọ́n sì pọ̀ jù yín lọ kúrò.+
23 Jèhófà máa lé gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè yìí kúrò níwájú yín,+ ẹ sì máa lé àwọn orílẹ̀-èdè tó tóbi, tí wọ́n sì pọ̀ jù yín lọ kúrò.+