-
Jóṣúà 19:49, 50Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
49 Bí wọ́n ṣe pín àwọn ilẹ̀ tí wọ́n jogún náà tán nìyí gẹ́gẹ́ bí àwọn ìlú tó wà níbẹ̀. Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wá fún Jóṣúà ọmọ Núnì ní ogún láàárín wọn. 50 Bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ, wọ́n fún un ní ìlú tó béèrè, ìyẹn Timunati-sírà,+ ní agbègbè olókè Éfúrémù, ó kọ́ ìlú náà, ó sì ń gbé inú rẹ̀.
-