Nọ́ńbà 14:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 “‘“Àwọn ọmọ yín tí ẹ sọ pé wọ́n máa kó+ lẹ́rú ni màá mú débẹ̀, wọ́n á sì mọ ilẹ̀ tí ẹ kọ̀+ náà.