-
Àwọn Onídàájọ́ 9:28, 29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Gáálì ọmọ Ébédì wá sọ pé: “Ta ni Ábímélékì, ta sì ni Ṣékémù tí a fi máa sìn ín? Ṣebí òun ni ọmọ Jerubáálì?+ Ṣebí Sébúlù ni kọmíṣọ́nnà rẹ̀? Ẹ máa sin àwọn ọkùnrin Hámórì, bàbá Ṣékémù! Àmọ́ kí ló dé tí a fi máa sin òun? 29 Ká ní àwọn èèyàn yìí wà lábẹ́ àṣẹ mi ni, ṣe ni ǹ bá yọ Ábímélékì nípò.” Ó wá sọ fún Ábímélékì pé: “Kó ọmọ ogun jọ sí i, kí o sì jáde wá.”
-