2 Sámúẹ́lì 11:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Àbí, ta ló pa Ábímélékì+ ọmọ Jerubéṣétì?*+ Ṣé kì í ṣe obìnrin ló ju ọlọ lù ú láti orí ògiri tí ó fi kú ní Tébésì? Kí ló dé tí ẹ fi sún mọ́ ògiri náà tó bẹ́ẹ̀?’ Kí o wá sọ pé, ‘Ìránṣẹ́ rẹ Ùráyà ọmọ Hétì náà kú.’”
21 Àbí, ta ló pa Ábímélékì+ ọmọ Jerubéṣétì?*+ Ṣé kì í ṣe obìnrin ló ju ọlọ lù ú láti orí ògiri tí ó fi kú ní Tébésì? Kí ló dé tí ẹ fi sún mọ́ ògiri náà tó bẹ́ẹ̀?’ Kí o wá sọ pé, ‘Ìránṣẹ́ rẹ Ùráyà ọmọ Hétì náà kú.’”