-
Àwọn Onídàájọ́ 19:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Àmọ́ ọ̀gá rẹ̀ sọ fún un pé: “Kò yẹ ká dúró ní ìlú àwọn àjèjì, àwọn tí kì í ṣe ọmọ Ísírẹ́lì. Ká máa lọ títí a fi máa dé Gíbíà.”+
-
-
Àwọn Onídàájọ́ 19:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Wọ́n wá ń bá ìrìn àjò wọn lọ, oòrùn sì ti ń wọ̀ nígbà tí wọ́n ń sún mọ́ Gíbíà, tó jẹ́ ti Bẹ́ńjámínì.
-