ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àwọn Onídàájọ́ 19:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Bí wọ́n ṣe ń gbádùn ara wọn, àwọn ọkùnrin kan tí kò ní láárí nínú ìlú yí ilé náà ká, wọ́n sì ń gbá ilẹ̀kùn, wọ́n ń sọ fún bàbá arúgbó tó ni ilé náà pé: “Mú ọkùnrin tó wá sínú ilé rẹ jáde, ká lè bá a lò pọ̀.”+

  • Àwọn Onídàájọ́ 19:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Ṣùgbọ́n àwọn ọkùnrin náà kò dá a lóhùn. Torí náà, ọkùnrin náà mú wáhàrì rẹ̀+ jáde fún wọn. Wọ́n fipá bá a lò pọ̀, wọ́n sì ṣe obìnrin náà ṣúkaṣùka ní gbogbo òru títí di àárọ̀. Wọ́n wá ní kó máa lọ nígbà tí ilẹ̀ ń mọ́ bọ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́