-
Àwọn Onídàájọ́ 20:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì wá jáde lọ gbógun ja Bẹ́ńjámínì; wọ́n tò lọ́wọ̀ọ̀wọ́ láti gbógun jà wọ́n ní Gíbíà.
-
-
Àwọn Onídàájọ́ 20:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Àmọ́ àwọn ọmọ ogun Ísírẹ́lì fi hàn pé àwọn nígboyà, wọ́n bá tún tò lọ́wọ̀ọ̀wọ́ láti gbógun jà wọ́n ní ibì kan náà bíi ti ọjọ́ àkọ́kọ́.
-