Jóṣúà 11:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Jóṣúà ṣẹ́gun gbogbo ilẹ̀ yìí, agbègbè olókè, gbogbo Négébù,+ gbogbo ilẹ̀ Góṣénì, Ṣẹ́fẹ́là,+ Árábà+ àti agbègbè olókè Ísírẹ́lì àti Ṣẹ́fẹ́là rẹ̀,* Jóṣúà 15:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Èyí ni ogún ẹ̀yà Júdà ní ìdílé-ìdílé. Jóṣúà 15:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Ní Ṣẹ́fẹ́là,+ àwọn ìlú náà ni: Éṣítáólì, Sórà,+ Áṣínà,
16 Jóṣúà ṣẹ́gun gbogbo ilẹ̀ yìí, agbègbè olókè, gbogbo Négébù,+ gbogbo ilẹ̀ Góṣénì, Ṣẹ́fẹ́là,+ Árábà+ àti agbègbè olókè Ísírẹ́lì àti Ṣẹ́fẹ́là rẹ̀,*