-
Rúùtù 1:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Nígbà tó yá, Élímélékì ọkọ Náómì kú, ó wá ku obìnrin náà àti àwọn ọmọ rẹ̀ méjèèjì.
-
-
Rúùtù 1:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ méjèèjì, Málónì àti Kílíónì kú. Bí obìnrin náà ò ṣe ní ọkọ àti ọmọ mọ́ nìyẹn.
-