Rúùtù 1:3, 4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nígbà tó yá, Élímélékì ọkọ Náómì kú, ó wá ku obìnrin náà àti àwọn ọmọ rẹ̀ méjèèjì. 4 Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ náà fẹ́ ìyàwó láàárín àwọn ará Móábù. Ọ̀kan ń jẹ́ Ọ́pà, èkejì sì ń jẹ́ Rúùtù.+ Nǹkan bí ọdún mẹ́wàá ni wọ́n fi gbé ibẹ̀.
3 Nígbà tó yá, Élímélékì ọkọ Náómì kú, ó wá ku obìnrin náà àti àwọn ọmọ rẹ̀ méjèèjì. 4 Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ náà fẹ́ ìyàwó láàárín àwọn ará Móábù. Ọ̀kan ń jẹ́ Ọ́pà, èkejì sì ń jẹ́ Rúùtù.+ Nǹkan bí ọdún mẹ́wàá ni wọ́n fi gbé ibẹ̀.