Ẹ́kísódù 23:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 “O ò gbọ́dọ̀ ni àjèjì lára. Ẹ mọ bó ṣe máa ń rí kéèyàn jẹ́ àjèjì,* torí àjèjì lẹ jẹ́ ní ilẹ̀ Íjíbítì.+ Léfítíkù 19:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Kí ẹ máa ṣe àjèjì tó ń bá yín gbé bí ọmọ ìbílẹ̀;+ kí ẹ nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ bí ara yín, torí àjèjì lẹ jẹ́ ní ilẹ̀ Íjíbítì.+ Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín.
9 “O ò gbọ́dọ̀ ni àjèjì lára. Ẹ mọ bó ṣe máa ń rí kéèyàn jẹ́ àjèjì,* torí àjèjì lẹ jẹ́ ní ilẹ̀ Íjíbítì.+
34 Kí ẹ máa ṣe àjèjì tó ń bá yín gbé bí ọmọ ìbílẹ̀;+ kí ẹ nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ bí ara yín, torí àjèjì lẹ jẹ́ ní ilẹ̀ Íjíbítì.+ Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín.