Léfítíkù 19:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 “‘Tí ẹ bá ń kórè oko yín, ẹ ò gbọ́dọ̀ kárúgbìn eteetí oko yín tán, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ pèéṣẹ́* irè oko yín.+ Rúùtù 2:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Rúùtù ará Móábù sọ fún Náómì pé: “Jọ̀wọ́, jẹ́ kí n lọ sí oko, kí n lè pèéṣẹ́*+ lára ṣírí ọkà lọ́dọ̀ ẹnikẹ́ni tó bá ṣojúure sí mi.” Torí náà, Náómì sọ fún un pé: “Lọ, ọmọ mi.”
9 “‘Tí ẹ bá ń kórè oko yín, ẹ ò gbọ́dọ̀ kárúgbìn eteetí oko yín tán, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ pèéṣẹ́* irè oko yín.+
2 Rúùtù ará Móábù sọ fún Náómì pé: “Jọ̀wọ́, jẹ́ kí n lọ sí oko, kí n lè pèéṣẹ́*+ lára ṣírí ọkà lọ́dọ̀ ẹnikẹ́ni tó bá ṣojúure sí mi.” Torí náà, Náómì sọ fún un pé: “Lọ, ọmọ mi.”